Luke 6:12

Àwọn aposteli méjìlá

12 a bNi ọ̀kan nínú àwọn ọjọ́ wọ̀n-ọn-nì, Jesu lọ sí orí òkè láti gbàdúrà, ó sì fi gbogbo òru náà gbàdúrà sí Ọlọ́run.
Copyright information for YorBMYO